ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 12

1 Ranti ẹlẹ́dàá rẹ ní ìgbà èwe rẹ, kí ọjọ́ ibi tó dé, kí ọjọ́ ogbó rẹ tó súnmọ́ etílé, nígbà tí o óo wí pé, “N kò ní inú…

ORIN SOLOMONI 1

1 Àwọn orin tí ó dùn jùlọ tí Solomoni kọ nìwọ̀nyí: Orin Kinni 2 Wá fi ẹnu kò mí lẹ́nu, nítorí ìfẹ́ rẹ dára ju ọtí waini lọ. 3 Òróró…

ORIN SOLOMONI 2

1 Òdòdó Ṣaroni ni mí, ati òdòdó Lílì tí ó wà ninu àfonífojì. 2 Bí òdòdó lílì ti rí láàrin ẹ̀gún, ni olólùfẹ́ mi rí láàrin àwọn ọmọge. 3 Bí…

ORIN SOLOMONI 3

1 Mo wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́, lórí ibùsùn mi lálẹ́, mo wá a, ṣugbọn n kò rí i; mo pè é, ṣugbọn kò dáhùn. 2 N óo dìde…

ORIN SOLOMONI 4

1 Wò ó! O dára gan-an ni, olólùfẹ́ mi, ẹwà rẹ pọ̀. Ẹyinjú rẹ dàbí ti àdàbà lábẹ́ ìbòjú rẹ, irun orí rẹ dàbí ọ̀wọ́ ewúrẹ́, tí wọn ń sọ̀kalẹ̀…

ORIN SOLOMONI 5

1 Mo wọ inú ọgbà mi, arabinrin mi, iyawo mi. Mo kó òjíá ati àwọn turari olóòórùn dídùn mi jọ, mo jẹ afárá oyin mi, pẹlu oyin inú rẹ̀, mo…

ORIN SOLOMONI 6

1 Níbo ni olùfẹ́ rẹ lọ, ìwọ, arẹwà jùlọ láàrin àwọn obinrin? Níbo ni olùfẹ́ rẹ yà sí, kí á lè bá ọ wá a? 2 Olùfẹ́ mi ti lọ…

ORIN SOLOMONI 7

1 Ẹsẹ̀ rẹ ti dára tó ninu bàtà, ìwọ, ọmọ aládé. Itan rẹ dàbí ohun ọ̀ṣọ́, tí ọlọ́gbọ́n oníṣọ̀nà ṣe. 2 Ìdodo rẹ dàbí abọ́, tí kì í gbẹ fún…

ORIN SOLOMONI 8

1 Ìbá wù mí kí o jẹ́ ọmọ ìyá mi ọkunrin, kí ó jẹ́ pé ọmú kan náà ni a jọ mú dàgbà. Bí mo bá pàdé rẹ níta, tí…

AISAYA 1

1 Ìran tí Aisaya ọmọ Amosi rí sí Juda ati Jerusalẹmu nìyí, nígbà ayé Usaya, Jotamu, Ahasi, ati Hesekaya, àwọn ọba Juda. OLUWA Bá Àwọn Eniyan Rẹ̀ Wí 2 Máa…