AISAYA 32
Ọba tí ó ṣe é gbẹ́kẹ̀lé 1 Wò ó! Ọba kan yóo jẹ pẹlu òdodo, àwọn ìjòyè yóo sì máa ṣe àkóso pẹlu ẹ̀tọ́. 2 Olukuluku yóo dàbí ibi ààbò…
Ọba tí ó ṣe é gbẹ́kẹ̀lé 1 Wò ó! Ọba kan yóo jẹ pẹlu òdodo, àwọn ìjòyè yóo sì máa ṣe àkóso pẹlu ẹ̀tọ́. 2 Olukuluku yóo dàbí ibi ààbò…
Adura fún Ìrànlọ́wọ́ 1 O gbé! Ìwọ tí ń panirun, tí ẹnìkan kò parun, ìwọ tí ò ń hùwà ọ̀dàlẹ̀ nígbà tí ẹnìkan kò dà ọ́. Ìgbà tí o bá…
Ọlọrun Yóo Jẹ Àwọn Ọ̀tá Rẹ̀ níyà 1 Ẹ súnmọ́ ibí, kí ẹ wá gbọ́, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè, ẹ tẹ́tí sílẹ̀, gbogbo ẹ̀yin eniyan. Kí ilẹ̀ gbọ́ ati gbogbo ohun tí…
Ọ̀nà Ìwà Mímọ́ 1 Inú aṣálẹ̀ ati ilẹ̀ gbígbẹ yóo dùn, aṣálẹ̀ yóo yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, yóo rúwé, yóo sì tanná. 2 Nítòótọ́ yóo tanná bí òdòdó, yóo yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, yóo…
Àwọn Ará Asiria Halẹ̀ mọ́ Jerusalẹmu 1 Ní ọdún kẹrinla tí Ọba Hesekaya jọba, Senakeribu, ọba Asiria gbógun ti gbogbo ìlú olódi Juda, ó sì kó wọn. 2 Ọba Asiria…
Ọba Bèèrè Ìmọ̀ràn lọ́wọ́ Aisaya 1 Nígbà tí Hesekaya ọba gbọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó fi aṣọ ọ̀fọ̀ bora, ó sì wọ inú ilé OLUWA lọ. 2 Ó…
Àìsàn Hesekaya ati Ìmúláradá Rẹ̀ 1 Ní àkókò náà, Hesekaya ṣàìsàn, àìsàn náà pọ̀; ó fẹ́rẹ̀ kú. Aisaya wolii, ọmọ Amosi tọ̀ ọ́ wá ní ọjọ́ kan, ó wí fún…
Ọba Babiloni kọ ìwé kí Hesekaya 1 Ní àkókò náà Merodaki Baladani ọmọ Baladani, ọba Babiloni, fi ìwé ati ẹ̀bùn rán àwọn ikọ̀ kan sí Hesekaya, nítorí ó gbọ́ pé…
Ọ̀rọ̀ Ìtùnú fún Àwọn Ọmọ Israẹli 1 Ọlọrun yín ní, “Ẹ tù wọ́n ninu, ẹ tu àwọn eniyan mi ninu. 2 Ẹ bá Jerusalẹmu sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ ẹ ké sí i…
Ọlọrun fún Israẹli ní Ìdánilójú 1 “Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́, kí ẹ sì gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, ẹ̀yin erékùṣù, kí àwọn eniyan gba agbára kún agbára wọn, kí wọ́n súnmọ́ ìtòsí, kí…