AISAYA 52
Ọlọrun Yóo Gba Jerusalẹmu 1 Jí, Sioni, jí! Gbé agbára rẹ wọ̀ bí aṣọ, gbé ẹwà rẹ wọ̀ bí ẹ̀wù, ìwọ Jerusalẹmu, ìlú mímọ́; nítorí àwọn aláìkọlà ati aláìmọ́, kò…
Ọlọrun Yóo Gba Jerusalẹmu 1 Jí, Sioni, jí! Gbé agbára rẹ wọ̀ bí aṣọ, gbé ẹwà rẹ wọ̀ bí ẹ̀wù, ìwọ Jerusalẹmu, ìlú mímọ́; nítorí àwọn aláìkọlà ati aláìmọ́, kò…
1 Ta ló lè gba ìyìn tí a rò gbọ́? Ta ni a ti fi agbára OLUWA hàn? 2 Ó dàgbà níwájú rẹ̀ bí nǹkan ọ̀gbìn tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ rúwé…
Ìfẹ́ OLUWA sí Israẹli 1 Máa kọrin! Ìwọ àgàn tí kò bímọ. Máa kọrin sókè, ìwọ tí kò rọbí rí. Nítorí ọmọ ẹni tí ọkọ ṣátì pọ̀, ju ọmọ ẹni…
Àánú Ọlọrun 1 OLUWA ní, “Gbogbo ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ, ẹ máa bọ̀ níbi tí omi wà; bí ẹ kò tilẹ̀ lówó lọ́wọ́, ẹ wá ra oúnjẹ kí ẹ…
Gbogbo Orílẹ̀-Èdè ni yóo Wà lára Àwọn Eniyan Ọlọrun 1 OLUWA ní: “Ẹ máa dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́, kí ẹ sì máa ṣe òdodo; nítorí ìgbàlà mi yóo dé láìpẹ́, ẹ…
OLUWA Dá Ìwà Ìbọ̀rìṣà Israẹli lẹ́bi 1 Olódodo ń ṣègbé, kò sí ẹni tí ó fi ọkàn sí i. A mú àwọn olótìítọ́ kúrò, kò sì sí ẹni tí ó…
Ààwẹ̀ Tòótọ́ 1 “Kígbe sókè, má dákẹ́, ké sókè bíi fèrè ogun, sọ ìrékọjá àwọn eniyan mi fún wọn ní àsọyé, sọ ẹ̀ṣẹ̀ ilé Jakọbu fún wọn. 2 Nítòótọ́ ni…
Wolii Lòdì sí Ẹ̀ṣẹ̀ Àwọn Eniyan 1 Wò ó! Agbára OLUWA kò dínkù, tí ó fi lè gbani là, etí rẹ̀ kò di, tí kò fi ní gbọ́. 2 Ṣugbọn…
Ògo Ọjọ́ Iwájú Jerusalẹmu 1 Dìde, tan ìmọ́lẹ̀; nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé, ògo OLUWA sì ti tàn sára rẹ. 2 Nítorí òkùnkùn yóo bo ayé mọ́lẹ̀, òkùnkùn biribiri yóo…
Ìròyìn Ayọ̀ Ìdáǹdè 1 Ẹ̀mí OLUWA, Ọlọrun tí bà lé mi, nítorí ó ti fi àmì òróró yàn mí, láti mú ìròyìn ayọ̀ wá fún àwọn tí a ni lára….