JEREMAYA 16
Ìfẹ́ OLUWA ní Ìgbésí Ayé Jeremaya 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “O kò gbọdọ̀ fẹ́ iyawo tabi kí o bímọ ní ibí yìí. 3 Nítorí ohun…
Ìfẹ́ OLUWA ní Ìgbésí Ayé Jeremaya 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “O kò gbọdọ̀ fẹ́ iyawo tabi kí o bímọ ní ibí yìí. 3 Nítorí ohun…
Ẹ̀ṣẹ̀ ati Ìjìyà Juda 1 OLUWA ní, “Gègé irin ni a fi kọ ẹ̀ṣẹ̀ Juda sílẹ̀ gègé òkúta dayamọndi ni a sì fi kọ ọ́ sí ọkàn yín, ati sí…
Jeremaya nílé Amọ̀kòkò 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Dìde, lọ sí ilé amọ̀kòkò, níbẹ̀ ni óo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ bá ọ sọ.” 3 Mo…
Ìgò Amọ̀ Tí Ó Fọ́ 1 OLUWA ní kí n lọ ra ìgò amọ̀ kan, kí n mú díẹ̀ ninu àwọn àgbààgbà ìlú ati àwọn bíi mélòó kan ninu àwọn…
Ìjà láàrin Jeremaya ati Paṣuri Alufaa 1 Nígbà tí Paṣuri alufaa, ọmọ Imeri, tí ó jẹ́ olórí àwọn olùṣọ́ ilé OLUWA, gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ, 2 ó ní…
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Ìṣubú Jerusalẹmu 1 Ọ̀rọ̀ tí Jeremaya gbọ́ lẹ́nu OLUWA nìyí nígbà tí ọba Sedekaya rán Paṣuri, ọmọ Malikaya, ati alufaa Sefanaya, ọmọ Maaseaya, sí i; 2 tí ọba…
Iṣẹ́ tí Jeremaya Jẹ́ fún Ìdílé Ọba Juda 1 OLUWA sọ fún mi pé, kí n lọ sí ilé ọba Juda kí n sọ fún un níbẹ̀ pé, 2 “Gbọ́…
Ìrètí Ọjọ́ Iwájú 1 OLUWA ní, “Àwọn olùṣọ́-aguntan tí wọn ń tú àwọn agbo aguntan mi ká, tí wọn ń run wọ́n gbé!” 2 Nítorí náà, OLUWA, Ọlọrun Israẹli sọ…
Apẹ̀rẹ̀ Èso Ọ̀pọ̀tọ́ Meji 1 Lẹ́yìn tí Nebukadinesari, ọba Babiloni ti kó Jehoiakini ọba Juda, ọmọ Jehoiakimu kúrò ní ìlú Jerusalẹmu lọ sí Babiloni, pẹlu àwọn ìjòyè Juda, ati àwọn…
Àwọn Ọ̀tá láti Ìhà Àríwá 1 Ní ọdún kẹrin tí Jehoiakimu, ọmọ Josaya jọba ní Juda, tí ó jẹ́ ọdún kinni tí Nebukadinesari jọba Babiloni, Jeremaya wolii gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA…