JEREMAYA 26
A Pe Jeremaya Lẹ́jọ́ 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Jehoiakimu ọba Juda, ọmọ Josaya, 2 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀; ó ní, “Dúró sí gbọ̀ngàn ilé OLUWA, kí o sọ gbogbo ọ̀rọ̀…
A Pe Jeremaya Lẹ́jọ́ 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Jehoiakimu ọba Juda, ọmọ Josaya, 2 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀; ó ní, “Dúró sí gbọ̀ngàn ilé OLUWA, kí o sọ gbogbo ọ̀rọ̀…
Jeremaya Kọrùn Bọ Àjàgà 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekaya, ọba Juda, ọmọ Josaya, OLUWA bá èmi Jeremaya sọ̀rọ̀; ó ní: 2 “Ṣe àjàgà kan pẹlu okùn rẹ̀ kí o sì…
Wolii Jeremaya ati Wolii Hananaya 1 Ní ọdún kan náà, ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekaya, ọba Juda, ní oṣù karun-un ọdún kẹrin, Hananaya wolii ọmọ Aṣuri, tí ó wá láti Gibeoni…
Lẹta Jeremaya sí Àwọn Tí Ogun Kó Lọ sí Babiloni 1 Jeremaya wolii kọ ìwé kan ranṣẹ láti Jerusalẹmu, ó kọ ọ́ sí àwọn àgbààgbà láàrin àwọn tí a kó…
Ìlérí OLUWA fún Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 OLUWA Ọlọrun Israẹli bá Jeremaya sọ̀rọ̀: 2 Ó ní, “Kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti sọ fún ọ sinu ìwé, 3 nítorí pé…
Israẹli Pada sílé 1 OLUWA ní, “Àkókò ń bọ̀ tí n óo jẹ́ Ọlọrun gbogbo ìdílé Israẹli, tí àwọn náà yóo sì jẹ́ eniyan mi. 2 Àwọn tí wọ́n bọ́…
Jeremaya Ra Ilẹ̀ 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ọdún kẹwaa tí Sedekaya jọba ní Juda, tí ó jẹ́ ọdún kejidinlogun tí Nebukadinesari jọba. 2 Àwọn ọmọ ogun Babiloni dó…
Ìlérí Ìrètí Mìíràn 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ lẹẹkeji, nígbà tí ó ṣì wà ní ẹ̀wọ̀n, ní àgbàlá àwọn tí ń ṣọ́ ààfin. 2 OLUWA tí ó dá ayé, tí…
Iṣẹ́ tí A Rán sí Sedekaya 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá Jeremaya sọ nìyí, nígbà tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ati gbogbo ìjọba ayé tí…
Jeremaya ati Àwọn Ọmọ Rekabu 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ìgbà ayé Jehoiakimu ọmọ Josaya, ọba Juda; ó ní, 2 “Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rekabu kí o bá…