JEREMAYA 46
Nebukadinesari ṣẹgun Ijipti ní Kakemiṣi 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá Jeremaya wolii sọ nípa àwọn orílẹ̀-èdè nìyí. 2 Ọ̀rọ̀ lórí Ijipti: Nípa àwọn ọmọ ogun Farao Neko, ọba Ijipti, tí…
Nebukadinesari ṣẹgun Ijipti ní Kakemiṣi 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá Jeremaya wolii sọ nípa àwọn orílẹ̀-èdè nìyí. 2 Ọ̀rọ̀ lórí Ijipti: Nípa àwọn ọmọ ogun Farao Neko, ọba Ijipti, tí…
Iṣẹ́ tí OLUWA Rán sí Àwọn Ará Filistia 1 OLUWA bá Jeremaya wolii sọ̀rọ̀ nípa Filistini kí Farao tó ṣẹgun Gasa, 2 Ó ní, “Wò ó, omi kan ń ru…
Ìparun Moabu 1 OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli sọ nípa Moabu pé, “Nebo gbé nítorí yóo di ahoro! Ojú yóo ti Kiriataimu nítorí ogun óo kó o; ìtìjú yóo…
Ìdájọ́ OLUWA Lórí Amoni 1 Ohun tí OLUWA sọ nípa àwọn ará Amoni nìyí: Ó ní, “Ṣé Israẹli kò lọ́mọ ni? Tabi kò ní àrólé? Kí ló dé tí àwọn…
Ogun kó Babiloni 1 OLUWA bá wolii Jeremaya sọ̀rọ̀ nípa Babiloni ní ilẹ̀ àwọn ará Kalidea pé: 2 “Kéde láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ta àsíá, kí o sì kéde. Má fi…
Ọlọrun Tún Dá Babiloni lẹ́jọ́ sí i 1 OLUWA ní, “Wò ó! N óo gbé ẹ̀mí apanirun kan dìde sí Babiloni, ati sí àwọn ará Kalidea; 2 n óo rán…
Ìṣubú Jerusalẹmu 1 Ẹni ọdún mọkanlelogun ni Sedekaya nígbà tí ó jọba, ọdún mọkanla ni ó sì fi wà lórí oyè ní Jerusalẹmu. Hamutali, ọmọ Jeremaya ará Libina ni ìyá…
Ìbànújẹ́ Jerusalẹmu 1 Ẹ wò ó bí ìlú tí ó kún fún eniyan tẹ́lẹ̀ ti di ahoro, tí ó wá dàbí opó! Ìlú tí ó tóbi láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀!…
Ìyà Tí OLUWA Fi Jẹ Jerusalẹmu 1 Ẹ wò bí OLUWA ti fi ibinu fi ìkùukùu bo Sioni mọ́lẹ̀. Ó ti wọ́ ògo Israẹli lu láti òkè ọ̀run sórí ilẹ̀…
Ìjìyà, Ìrònúpìwàdà ati Ìrètí 1 Èmi ni mo mọ bí eniyan tií rí ìpọ́njú, tí mo mọ bí Ọlọrun tií fi ibinu na eniyan ní pàṣán. 2 Ó lé mi…