ISIKIẸLI 9

Wọ́n Jẹ Jerusalẹmu Níyà 1 Lẹ́yìn náà, Ọlọrun kígbe sí mi létí, ó ní, “Ẹ súnmọ́bí, ẹ̀yin tí ẹ óo pa ìlú yìí run, kí olukuluku mú nǹkan ìjà rẹ̀…

ISIKIẸLI 10

Ògo OLUWA Kúrò Ninu Tẹmpili Náà 1 Lẹ́yìn náà, mo wo orí àwọn Kerubu, mo rí kinní kan róbótó róbótó, wọ́n dàbí òkúta safire, ìrísí wọn dàbí ìtẹ́. 2 Ọlọrun…

ISIKIẸLI 11

(OLUWA Bá Jerusalẹmu Wí) 1 Ẹ̀mí gbé mi lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn. Àwọn ọkunrin mẹẹdọgbọn kan wà lẹ́nu ọ̀nà náà, mo…

ISIKIẸLI 12

Wolii Gẹ́gẹ́ Bí Ẹni Tí Ó sá fógun 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ààrin àwọn olóríkunkun ni o wà: àwọn tí wọ́n ní ojú,…

ISIKIẸLI 13

Ìran Ibi Nípa Àwọn Ọkunrin Wolii Èké 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn wolii Israẹli. Sọ àsọtẹ́lẹ̀, kí o sì wí…

ISIKIẸLI 14

Ọlọrun Fi Ìbọ̀rìṣà Gégùn-ún 1 Àwọn àgbààgbà Israẹli kan tọ̀ mí wá, wọ́n jókòó siwaju mi. 2 OLUWA bá bá mi sọ̀rọ̀, 3 ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọkunrin…

ISIKIẸLI 15

Òwe Nípa Igi Àjàrà 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ọ̀nà wo ni ẹ̀ka igi àjàrà gbà dára ju ẹ̀ka igi yòókù lọ; àní igi…

ISIKIẸLI 16

Ìtàn Jerusalẹmu 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, fi nǹkan ìríra tí Jerusalẹmu ń ṣe hàn án, 3 kí o sì sọ fún un…

ISIKIẸLI 17

Òwe Nípa Àwọn Ẹyẹ Idì ati Àjàrà 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, pa àlọ́ kan kí o sì fi òwe bá àwọn ọmọ…

ISIKIẸLI 18

Iṣẹ́ Ẹnìkọ̀ọ̀kan 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó bi mí pé: 2 “Kí ni ẹ rí tí ẹ fi ń pa irú òwe yìí nípa ilẹ̀ Israẹli, tí ẹ̀…