ISIKIẸLI 39

A Ṣẹgun Gogu 1 OLUWA Ọlọrun ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá Gogu wí, sọ fún un pé OLUWA Ọlọrun ní: ‘Mo lòdì sí ọ́, ìwọ Gogu, ìwọ tí…

ISIKIẸLI 40

Isikiẹli Lọ sí Jerusalẹmu Lójú Ìran 1 Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kinni, ọdún kẹẹdọgbọn tí a ti wà ní ìgbèkùn, tíí ṣe ọdún kẹrinla tí ogun fọ́ ìlú Jerusalẹmu, agbára…

ISIKIẸLI 41

1 Lẹ́yìn náà ó mú mi lọ sí ibi mímọ́, ó wọn àtẹ́rígbà rẹ̀, ìbú rẹ̀ ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji jẹ́ igbọnwọ mẹfa (mita 3). 2 Ìbú ẹnu ọ̀nà àbáwọlé…

ISIKIẸLI 42

Àwọn Ilé Meji Tí Wọ́n Wà ní Ẹ̀gbẹ́ Tẹmpili náà 1 Lẹ́yìn náà ó mú mi jáde, ó mú mi wọ inú gbọ̀ngàn ti inú lápá ìhà àríwá, ó sì…

ISIKIẸLI 43

Ọlọrun Pada Sinu Tẹmpili 1 Lẹ́yìn náà, ó mú mi wá sí ẹnu ọ̀nà tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn. 2 Wò ó! Ìtànṣán ògo Ọlọrun Israẹli yọ láti…

ISIKIẸLI 44

Lílo Ẹnu Ọ̀nà Ìlà Oòrùn 1 Lẹ́yìn náà ó mú mi wá sí ẹnu ọ̀nà ìta ibi mímọ́ tí ó kọjú sí ìlà oòrùn, ìlẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà náà wà ní…

ISIKIẸLI 45

Ìpín OLUWA ní Orílẹ̀-Èdè Náà 1 “Nígbà tí ẹ bá pín ilẹ̀ náà fún àwọn eniyan, ẹ ya ilẹ̀ kan sọ́tọ̀ fún OLUWA, tí yóo jẹ́ ilẹ̀ mímọ́. Gígùn rẹ̀…

ISIKIẸLI 46

Àwọn Ọba ati Àwọn Àjọ̀dún 1 OLUWA Ọlọrun ní, “Ẹnu ọ̀nà àgbàlá inú tí ó kọjú sí ìlà oòrùn gbọdọ̀ wà ní títì fún ọjọ́ mẹfa tí a fi ń…

ISIKIẸLI 47

Odò tí Ń Ṣàn láti Tẹmpili 1 Ọkunrin náà bá mú mi pada wá sí ẹnu ọ̀nà Tẹmpili, mo sì rí i tí omi kan ń sun láti abẹ́ ìlẹ̀kùn…

ISIKIẸLI 48

Pípín Ilẹ̀ Náà láàrin Àwọn Ẹ̀yà Israẹli 1 Orúkọ àwọn ẹ̀yà Israẹli nìwọ̀nyí: Ààlà ilẹ̀ náà ní ìhà àríwá bẹ̀rẹ̀ láti etíkun, ó lọ ní apá ọ̀nà Hẹtiloni dé àbáwọ…