AMOSI 2
Moabu 1 OLUWA ní: “Àwọn ará Moabu ń dẹ́ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀, dájúdájú, n óo jẹ wọ́n níyà; nítorí wọ́n sọná sí egungun ọba Edomu, wọ́n sun ún, ó jóná ráúráú….
Moabu 1 OLUWA ní: “Àwọn ará Moabu ń dẹ́ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀, dájúdájú, n óo jẹ wọ́n níyà; nítorí wọ́n sọná sí egungun ọba Edomu, wọ́n sun ún, ó jóná ráúráú….
1 Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA sọ nípa yín, gbogbo ẹ̀yin tí a kó jáde láti ilẹ̀ Ijipti: OLUWA ní, 2 “Ẹ̀yin nìkan ni mo mọ̀ láàrin…
1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin obinrin Samaria, ẹ̀yin tí ẹ sanra bíi mààlúù Baṣani, tí ẹ wà lórí òkè Samaria, tí ẹ̀ ń ni àwọn aláìní lára, tí ẹ̀…
Ìpè sí Ìrònúpìwàdà 1 Ẹ fetí sí orin arò tí mò ń kọ le yín lórí, ẹ̀yin ìdílé Israẹli: 2 Israẹli, ọdọmọbinrin, ṣubú, kò ní lè dìde mọ́ lae. Ó…
Ìparun Israẹli 1 Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n wà ninu ìdẹ̀ra ní Sioni, ati àwọn tí wọn ń gbé orí òkè Samaria láìléwu, àwọn eniyan ńláńlá ní Israẹli, tí…
Ìran Nípa Eṣú 1 OLUWA Ọlọrun fi ìran kan hàn mí! Ó ń kó ọ̀wọ́ eṣú jọ ní àkókò tí koríko ìkẹyìn bẹ̀rẹ̀ sí yọ sókè, lẹ́yìn tí wọ́n ti…
Ìran Nípa Agbọ̀n Èso 1 OLUWA Ọlọrun, tún fi ìran mìíràn hàn mí. Lójú ìran, mo rí agbọ̀n èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn kan. 2 OLUWA bèèrè pé, “Amosi, kí ni ò…
Ìdájọ́ OLUWA 1 Mo rí OLUWA, ó dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ, ó pàṣẹ pé, “Lu àwọn òpó tẹmpili títí tí gbogbo àtẹ́rígbà rẹ̀ yóo fi mì tìtì, tí yóo sì wó…
OLUWA Yóo Jẹ Edomu Níyà 1 Ìran tí Ọbadaya rí nìyí, OLUWA Ọlọrun sọ nípa Edomu pé: A ti gbọ́ ìròyìn láti ọ̀dọ̀ OLUWA, ó sì ti rán iranṣẹ rẹ̀…
Jona Ṣe Àìgbọràn sí OLUWA 1 OLUWA bá Jona ọmọ Amitai sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Dìde, lọ sí Ninefe, ìlú ńlá nì, kéde, kí o sì kìlọ̀ fún wọn pé…