NAHUMU 1
1 Ọ̀rọ̀ OLUWA nìyí; tí a kọ sinu ìwé ìran tí Nahumu ará Elikoṣi rí nípa ìlú Ninefe. Ibinu OLUWA sí Ìlú Ninefe 2 OLUWA tíí jowú tíí sìí máa…
1 Ọ̀rọ̀ OLUWA nìyí; tí a kọ sinu ìwé ìran tí Nahumu ará Elikoṣi rí nípa ìlú Ninefe. Ibinu OLUWA sí Ìlú Ninefe 2 OLUWA tíí jowú tíí sìí máa…
Ìṣubú Ninefe 1 Atúniká ti gbógun tì ọ́, ìwọ Ninefe. Yan eniyan ṣọ́ ibi ààbò; máa ṣọ́nà, di àmùrè rẹ, kí o sì múra ogun. 2 (Nítorí OLUWA ti ṣetán…
1 Ìlú tí ń ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ gbé! Ìlú tí ó kún fún irọ́ ati ìkógun, tí àwọn adigunjalè kò fi ìgbà kan dáwọ́ dúró níbẹ̀! 2 Pàṣán ń ró,…
1 Ìran tí Ọlọrun fihan wolii Habakuku nìyí. Ìráhùn Habakuku sí Ọlọrun 2 OLUWA, yóo ti pẹ́ tó, tí n óo máa ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́; tí o kò…
Ìdáhùn OLUWA sí Habakuku 1 N óo dúró sí ibìkan lórí ilé-ìṣọ́, n óo máa wòran. N óo dúró, n óo máa retí ohun tí yóo sọ fún mi, ati…
Adura Habakuku 1 Adura tí wolii Habakuku kọ lórin nìyí: 2 OLUWA, mo ti gbọ́ òkìkí rẹ, mo sì bẹ̀rù iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Gbogbo bí ò ó tíí ṣe tí…
1 Èyí ni iṣẹ́ tí Ọlọrun rán Sefanaya, ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedalaya, ọmọ Amaraya, ọmọ Hesekaya ní àkókò ìjọba Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda. Ọjọ́ Ìdájọ́ Ọlọrun 2 OLUWA ní,…
Ìpè sí Ìrònúpìwàdà 1 Ẹ kó ara yín jọ, kí ẹ gbìmọ̀ pọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tí kò ní ìtìjú. 2 Kí á tó fẹ yín dànù, bí ìgbà tí afẹ́fẹ́…
Ẹ̀ṣẹ̀ Jerusalẹmu ati Ìràpadà Rẹ̀ 1 Ìwọ ìlú ọlọ̀tẹ̀, o gbé! Ìlú oníbàjẹ́ ati aninilára. 2 Ìlú tí kò gba ìmọ̀ràn ati ìbáwí, tí kò gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, tí kò sì…
OLUWA pàṣẹ láti tún Tẹmpili Kọ́ 1 Ní ọjọ́ kinni, oṣù kẹfa, ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA rán wolii Hagai sí Serubabeli, ọmọ Ṣealitieli, gomina ilẹ̀ Juda, ati sí Joṣua…