HAGAI 2

Ẹwà Tẹmpili Tuntun náà 1 Ní ọjọ́ kọkanlelogun oṣù keje, ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA tún sọ fún wolii Hagai, pé: 2 “Tún lọ sọ́dọ̀ Serubabeli ọmọ Ṣealitieli, gomina ilẹ̀…

SAKARAYA 1

OLUWA Pe Àwọn Eniyan Rẹ̀ Pada Sọ́dọ̀ 1 Ní oṣù kẹjọ, ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA rán wolii Sakaraya, ọmọ Berekaya, ọmọ Ido, sí àwọn ọmọ Israẹli; ó ní, 2…

SAKARAYA 2

Ìran nípa Okùn Ìwọ̀n 1 Bí mo tún ti gbé ojú sókè, mo rí ọkunrin kan tí ó mú okùn ìwọ̀n lọ́wọ́. 2 Mo bi í pé, “Níbo ni ò…

SAKARAYA 3

Ìran wolii náà nípa Olórí Alufaa 1 Lẹ́yìn náà, OLUWA fi Joṣua olórí alufaa hàn mí; ó dúró níwájú angẹli OLUWA, Satani sì dúró lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ̀ láti fi ẹ̀sùn…

SAKARAYA 4

Ìran nípa Ọ̀pá Fìtílà 1 Angẹli tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀ tún pada wá, ó jí mi bí ẹni pé mo sùn. 2 Ó bi mí pé kí ni…

SAKARAYA 5

Ìran nípa Ìwé Kíká Tí Ó Ń Fò 1 Mo tún gbé ojú sókè, mo bá rí ìwé kíká kan tí ń fò ní òfuurufú. 2 Angẹli náà bi mí…

SAKARAYA 6

Ìran nípa Àwọn Kẹ̀kẹ́ Ogun Mẹrin 1 Mo tún gbé ojú sókè, mo rí kẹ̀kẹ́ ogun mẹrin tí ń bọ̀ láàrin òkè meji; òkè idẹ ni àwọn òkè náà. 2…

SAKARAYA 7

OLUWA Kọ Ààwẹ̀ Àgàbàgebè 1 Ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsan-an, tíí ṣe oṣù Kisilefi, ní ọdún kẹrin ìjọba Dariusi, ni OLUWA rán mi níṣẹ́ yìí. 2 Àwọn ará Bẹtẹli rán…

SAKARAYA 8

Ọlọrun ṣèlérí láti Dá Ibukun Jerusalẹmu Pada 1 OLUWA àwọn ọmọ ogun tún bá mi sọ̀rọ̀ pé 2 Òun fẹ́ràn àwọn ará Sioni; nítorí náà ni inú òun ṣe ru…

SAKARAYA 9

Ìdájọ́ lórí Àwọn Orílẹ̀-Èdè Tí Wọ́n Wà ní Agbègbè Israẹli 1 OLUWA ní ilẹ̀ Hadiraki yóo jìyà, bẹ́ẹ̀ náà sì ni ìlú Damasku. Nítorí pé OLUWA ló ni àwọn ìlú…