MATIU 22

Òwe Àsè Igbeyawo 1 Jesu tún fi òwe bá wọn sọ̀rọ̀. Ó ní, 2 “Ìjọba ọ̀run dàbí ọba kan, tí ó ń gbeyawo fún ọmọ rẹ̀. 3 Ó rán àwọn…

MATIU 23

Jesu Bá Àwọn Amòfin ati Àwọn Farisi Wí 1 Jesu bá sọ fún àwọn eniyan ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, 2 “Àwọn amòfin ati àwọn Farisi ni olùtúmọ̀ òfin Mose….

MATIU 24

Jesu Sọtẹ́lẹ̀ nípa Wíwó Tẹmpili 1 Jesu jáde kúrò ninu Tẹmpili. Bí ó ti ń lọ, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá, wọ́n pe akiyesi rẹ̀ sí bí a ti ṣe kọ́…

MATIU 25

Òwe nípa Àwọn Wundia Mẹ́wàá 1 “Ní àkókò náà, ọ̀rọ̀ ìjọba ọ̀run yóo dàbí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí àwọn wundia mẹ́wàá, tí wọn gbé àtùpà wọn láti jáde lọ…

MATIU 26

Àwọn Juu dìtẹ̀ láti pa Jesu 1 Nígbà tí Jesu parí gbogbo ọ̀rọ̀ wọnyi, ó sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, 2 “Ẹ mọ̀ pé lẹ́yìn ọjọ́ meji ni Àjọ̀dún…

MATIU 27

Wọ́n fa Jesu lọ sọ́dọ̀ Pilatu 1 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, gbogbo àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbà ìlú jọ forí-korí nípa ọ̀ràn Jesu, kí wọ́n lè pa á. 2…

MATIU 28

Ajinde Jesu 1 Nígbà tí Ọjọ́ Ìsinmi ti kọjá, tí ilẹ̀ fẹ́rẹ̀ mọ́ ní ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, Maria Magidaleni ati Maria keji wá wo ibojì Jesu. 2 Ilẹ̀ mì tìtì,…

MAKU 1

Iwaasu Johanu Onítẹ̀bọmi 1 Bí ìyìn rere Jesu Kristi Ọmọ Ọlọrun ṣe bẹ̀rẹ̀ nìyí: 2 Gẹ́gẹ́ bí wolii Aisaya ti kọ ọ́ tẹ́lẹ̀ ni ó rí: “Ọlọrun ní, ‘Wò ó!…

MAKU 2

Jesu Wo Arọ Sàn 1 Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Jesu tún lọ sí Kapanaumu, àwọn eniyan gbọ́ pé ó wà ninu ilé kan. 2 Ọ̀pọ̀ eniyan bá wá péjọ sibẹ, wọ́n…

MAKU 3

Ọkunrin Tí Ọwọ́ Rẹ̀ Rọ 1 Jesu tún wọ inú ilé ìpàdé lọ. Ọkunrin kan wà níbẹ̀ tí ọwọ́ rẹ̀ kan rọ. 2 Àwọn kan wà tí wọn ń ṣọ́…